Yoruba Kùráánì

Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa ati ti tuu pelu ohun

fidio ifihan

Eero wa ni lati fun awon eniyan ni anfani ki ka Kurani Alaponle ni eede won (Oruko Ede) ki itumon ati agboye Kurani le wa ni a rowo to won, ni eyikeyi awoo won ati olaju won O le gbaa ohun elo yi ka le, o si tun le maa woo oju ewe Kurani Alaponle ni ede (Oruko Ede) pelu onaa ti o rorun ju lo, ati pelu onaa ti o se oju loin ti o si daa ra, e yi awon akose-monse nkan yiya ati i se Kurani lo so ni agabye se fi ko. E yi je ise agbese ti o je oofee ti ko si ni ipolongo ninu, ti o wa fun gbobgbo fun la ti maa loo, ni ti to ri Olohun.

li lo ohun elo Kurani lori Android ati iOS

I sa fihan Kurani pelu itumon ati ki kaa pelu itumon re ni ohun

Awon nkan esa ohun elo

  • FEATURING

    O rorun la ti lo

    O si tun ni fonti ti o mon ni won ba ti o si ni orisis agbara ti on te si waju

  • FEATURING

    Lẹsẹkẹsẹ ati wiwa iyara

    Iwadi yara-yara ninu awon oro Kurani Alaponle ati ninu awon oruko ogba oro ati eka-eka Kurani

  • FEATURING

    Ki ka Kurani.

    Ki ka Kurani. Je igbadun ki ka Kurani Alaponle ti a da ko lati ibi ti o se gbaa ra le ati e yi ti a se lo so lo na ti o daa raa.

  • FEATURING

    Awon itumon Kurani Alaponl

    Gbo Kurani Alaponle ni ede re peu bi awon itumon re se ti wa ni Ede.....

  • FEATURING

    Awon Ede orisisi

    Maa lo ohun elo yi pelu ede re ta bi ede miran ti o ni fe si laa ti maa wo Kurani.

  • FEATURING

    Ki ka Kurani

    Maa gbo ki ka Kurani Alaponle pelu ohun awon oluka Kurani to gba ju mo ati awon ti won man kaa Kurani pelu ohun dun-dun.

  • FEATURING

    Ti tumon Kurani pelu ohun

    Gbigbo itumon Kurani Alaponle pelu ohun ni ede....

  • FEATURING

    Ti tan ohun ti o loo si waju

    Ti tan ohun yi o fun ni awon anfani agbara ti o lo si waju gege bi pi paara e yi ti yi o ron oo lo wo laa ti ha Kurani Alaponle

  • FEATURING

    Ālā

    Fi fi awon āmi ibi a ti ri awon anfani ati sise idari won, ki o le rọrun la ti dari si awon aye lati duro ni awon amin (Āyah) ko kon.

  • FEATURING

    Nkan ti a yan laa yo

    Fi fi awon orisis amin (Āyah) ti a yan laa yo si be, ki o la sa re pa da si be ti o ba ya

  • FEATURING

    Fi fi irori ye si be

    Fi fi irori ati ironu si be laa rin ki ka Al-Kurani tabi ni igba ti a ban ka itumo re.

  • FEATURING

    pin pin nkan pelu elomiran

    Pin pin awon ami (Āyah) tabi awon itumon re pelu awon ọrẹ rẹ lati ibi awon ohun a tẹle ati awon ona ayelujara

  • FEATURING

    Mi mo nkan ni o na aara

    Sise a sa yan awon aawọ orisisi ati awon nkan yoro-yoro ti o se oju loin, ati mi mo nkan ni ti igba lode ti a mu ni ibi olaju awon elede Yoruba

[email protected]

Mail

  • Facebook
  • Twitter
  • Youtube
  • Vimeo
  • Google +

Si se asokale titu awon itumon Al-Kurani pelu ede Yoruba